16 Mo rí i pé ninu ayé yìí ibi tí ó yẹ kí ìdájọ́ òtítọ́ ati òdodo wà ibẹ̀ gan-an ni ìwà ìkà wà.
Ka pipe ipin Ìwé Oníwàásù 3
Wo Ìwé Oníwàásù 3:16 ni o tọ