17 Mo wí ní ọkàn ara mi pé, Ọlọrun yóo dájọ́ fún olódodo ati fún eniyan burúkú; nítorí ó ti yan àkókò fún ohun gbogbo ati fún iṣẹ́ gbogbo.
Ka pipe ipin Ìwé Oníwàásù 3
Wo Ìwé Oníwàásù 3:17 ni o tọ