Ìwé Oníwàásù 7:14 BM

14 Máa yọ̀ nígbà tí ó bá dára fún ọ, ṣugbọn nígbà tí nǹkan kò bá dára, máa ranti pé Ọlọrun ló ṣe mejeeji. Nítorí náà, eniyan kò lè mọ ohun tí ń bọ̀ wá ṣẹlẹ̀ lẹ́yìn ọ̀la.

Ka pipe ipin Ìwé Oníwàásù 7

Wo Ìwé Oníwàásù 7:14 ni o tọ