Ìwé Oníwàásù 7:15 BM

15 Ninu gbogbo ìgbé-ayé asán mi, mo ti rí àwọn nǹkan wọnyi: Mo ti rí olódodo tí ó ṣègbé ninu òdodo rẹ̀, mo sì ti rí eniyan burúkú tí ẹ̀mí rẹ̀ gùn, pẹlu bí ó ti ń ṣe ibi.

Ka pipe ipin Ìwé Oníwàásù 7

Wo Ìwé Oníwàásù 7:15 ni o tọ