23 Gbogbo nǹkan wọnyi ni mo ti fi ọgbọ́n wádìí. Mo sọ ninu ara mi pé, “Mo fẹ́ gbọ́n,” ṣugbọn ọgbọ́n jìnnà sí mi.
Ka pipe ipin Ìwé Oníwàásù 7
Wo Ìwé Oníwàásù 7:23 ni o tọ