Ìwé Oníwàásù 7:29 BM

29 Ẹ̀kọ́ tí mo rí kọ́ ni pé rere ni Ọlọrun dá eniyan, ṣugbọn àwọn ni wọ́n wá oríṣìíríṣìí ọ̀nà àrékérekè fún ara wọn.

Ka pipe ipin Ìwé Oníwàásù 7

Wo Ìwé Oníwàásù 7:29 ni o tọ