1 Ta ló dàbí ọlọ́gbọ́n? Ta ló sì mọ ìtumọ̀ nǹkan? Ọgbọ́n ní ń mú kí ojú ọlọ́gbọ́n máa dán, á mú kí ó tújúká kí ó gbàgbé ìṣòro.
Ka pipe ipin Ìwé Oníwàásù 8
Wo Ìwé Oníwàásù 8:1 ni o tọ