Kọrinti Kinni 10:17 BM

17 Nítorí burẹdi kan ni ó wà, ninu ara kan yìí ni gbogbo wa sì wà, nítorí ninu burẹdi kan ni gbogbo wa ti ń jẹ.

Ka pipe ipin Kọrinti Kinni 10

Wo Kọrinti Kinni 10:17 ni o tọ