Kọrinti Kinni 10:18 BM

18 Ẹ ṣe akiyesi ìṣe àwọn ọmọ Israẹli. Ṣebí àwọn tí ń jẹ ẹbọ ń jẹ ninu anfaani lílo pẹpẹ ìrúbọ fún ìsìn Ọlọrun?

Ka pipe ipin Kọrinti Kinni 10

Wo Kọrinti Kinni 10:18 ni o tọ