Kọrinti Kinni 14:34 BM

34 àwọn obinrin gbọdọ̀ panumọ́ ninu ìjọ. A kò gbà wọ́n láyè láti sọ̀rọ̀. Wọ́n níláti wà ní ipò ìtẹríba, gẹ́gẹ́ bí Òfin ti wí.

Ka pipe ipin Kọrinti Kinni 14

Wo Kọrinti Kinni 14:34 ni o tọ