Kọrinti Kinni 14:35 BM

35 Bí nǹkankan bá wà tí wọ́n fẹ́ mọ̀, kí wọ́n bi àwọn ọkọ wọn ní ilé. Ìtìjú ni fún obinrin láti sọ̀rọ̀ ninu ìjọ.

Ka pipe ipin Kọrinti Kinni 14

Wo Kọrinti Kinni 14:35 ni o tọ