Tẹsalonika Kinni 2:15 BM

15 Àwọn Juu yìí ni wọ́n pa Oluwa Jesu ati àwọn wolii, tí wọ́n sì fi inúnibíni lé wa jáde. Wọn kò ṣe ohun tí ó wu Ọlọrun, wọ́n sì ń lòdì sí àwọn ohun tí ó lè ṣe eniyan ní anfaani.

Ka pipe ipin Tẹsalonika Kinni 2

Wo Tẹsalonika Kinni 2:15 ni o tọ