Tẹsalonika Kinni 3:4 BM

4 Nítorí nígbà tí a wà lọ́dọ̀ yín, a ti sọ fun yín tẹ́lẹ̀ pé a níláti jìyà. Bẹ́ẹ̀ ni ó sì rí, bí ẹ̀yin náà ti mọ̀.

Ka pipe ipin Tẹsalonika Kinni 3

Wo Tẹsalonika Kinni 3:4 ni o tọ