Tẹsalonika Kinni 3:5 BM

5 Nítorí náà, èmi náà kò lè fi ara dà á mọ́, ni mo bá ranṣẹ láti wá wádìí nípa ìdúró yín, kí ó má baà jẹ́ pé olùdánwò ti dán yín wò, kí akitiyan wa má baà já sí òfo.

Ka pipe ipin Tẹsalonika Kinni 3

Wo Tẹsalonika Kinni 3:5 ni o tọ