A. Oni 1:25 YCE

25 O si fi ọ̀na atiwọ̀ ilu na hàn wọn, nwọn si fi oju idà kọlù ilu na; ṣugbọn nwọn jọwọ ọkunrin na ati gbogbo awọn ara ile rẹ̀ lọwọ lọ.

Ka pipe ipin A. Oni 1

Wo A. Oni 1:25 ni o tọ