A. Oni 1:9 YCE

9 Lẹhin na awọn ọmọ Juda si sọkalẹ lọ lati bá awọn ara Kenaani jà, ti ngbé ilẹ òke, ati ni Gusù, ati ni afonifoji nì.

Ka pipe ipin A. Oni 1

Wo A. Oni 1:9 ni o tọ