A. Oni 10:15 YCE

15 Awọn ọmọ Israeli si wi fun OLUWA pe, Awa ti ṣẹ̀: ohunkohun ti o ba tọ́ li oju rẹ ni ki o fi wa ṣe; sá gbà wa li oni yi, awa bẹ̀ ọ.

Ka pipe ipin A. Oni 10

Wo A. Oni 10:15 ni o tọ