A. Oni 11:11 YCE

11 Nigbana ni Jefta bá awọn àgba Gileadi lọ, awọn enia na si fi i jẹ́ olori ati balogun wọn: Jefta si sọ gbogbo ọ̀rọ rẹ̀ niwaju OLUWA ni Mispa.

Ka pipe ipin A. Oni 11

Wo A. Oni 11:11 ni o tọ