A. Oni 15:10 YCE

10 Awọn ọkunrin Juda si wipe, Nitori kili ẹnyin ṣe gòke tọ̀ wa wá? Nwọn si dahùn wipe, Lati dè Samsoni li awa ṣe wá, lati ṣe si i gẹgẹ bi on ti ṣe si wa.

Ka pipe ipin A. Oni 15

Wo A. Oni 15:10 ni o tọ