A. Oni 15:12 YCE

12 Nwọn si wi fun u pe, Awa sọkalẹ wá lati dè ọ, ki awa ki o le fi ọ lé awọn Filistini lọwọ. Samsoni si wi fun wọn pe, Ẹ bura fun mi, pe ẹnyin tikara nyin ki yio pa mi.

Ka pipe ipin A. Oni 15

Wo A. Oni 15:12 ni o tọ