A. Oni 17:5 YCE

5 Ọkunrin na Mika si ní ile-oriṣa kan, o si ṣe efodu, ati terafimu, o si yà ọkan ninu awọn ọmọ rẹ̀ ọkunrin sọtọ̀, ẹniti o si wa di alufa rẹ̀.

Ka pipe ipin A. Oni 17

Wo A. Oni 17:5 ni o tọ