A. Oni 18:22 YCE

22 Nigbati nwọn si lọ jìna si ile Mika, awọn ọkunrin ti o wà ninu ile wọnni ti o sunmọ ile Mika kó ara wọn jọ, nwọn si lé awọn ọmọ Dani bá.

Ka pipe ipin A. Oni 18

Wo A. Oni 18:22 ni o tọ