A. Oni 19:8 YCE

8 On si dide ni kùtukutu ọjọ́ karun lati lọ, baba ọmọbinrin na si wipe, Mo bẹ̀ ọ, tù ara rẹ lara, ki ẹ si duro titi di irọlẹ; awọn mejeji si jẹun.

Ka pipe ipin A. Oni 19

Wo A. Oni 19:8 ni o tọ