A. Oni 2:20 YCE

20 Ibinu OLUWA si rú si Israeli; o si wipe, Nitoriti orilẹ-ède yi ti re majẹmu mi kọja eyiti mo ti palaṣẹ fun awọn baba wọn, ti nwọn kò si gbọ́ ohùn mi;

Ka pipe ipin A. Oni 2

Wo A. Oni 2:20 ni o tọ