A. Oni 2:4 YCE

4 O si ṣe, nigbati angeli OLUWA sọ ọ̀rọ wọnyi fun gbogbo awọn ọmọ Israeli, awọn enia na si gbé ohùn wọn soke, nwọn si sọkun.

Ka pipe ipin A. Oni 2

Wo A. Oni 2:4 ni o tọ