A. Oni 20:1 YCE

1 NIGBANA ni gbogbo awọn ọmọ Israeli jade lọ, ijọ awọn enia si wọjọ pọ̀ bi ọkunrin kan, lati Dani lọ titi o fi dé Beeri-ṣeba, pẹlu ilẹ Gileadi, si ọdọ OLUWA ni Mispa.

Ka pipe ipin A. Oni 20

Wo A. Oni 20:1 ni o tọ