A. Oni 20:18 YCE

18 Awọn ọmọ Israeli si dide, nwọn si lọ si Beti-eli nwọn si bère lọdọ Ọlọrun, wipe, Tani ninu wa ti yio tètekọ gòke lọ ibá awọn ọmọ Benjamini jà? OLUWA si wipe, Juda ni yio tète gòke lọ.

Ka pipe ipin A. Oni 20

Wo A. Oni 20:18 ni o tọ