A. Oni 20:36 YCE

36 Bẹ̃li awọn ọmọ Benjamini wa ri pe a ṣẹgun wọn: nitoriti awọn ọkunrin Israeli bìsẹhin fun awọn ara Benjamini nitoriti nwọn gbẹkẹle awọn ti o wà ni ibùba, ti nwọn yàn si eti Gibea.

Ka pipe ipin A. Oni 20

Wo A. Oni 20:36 ni o tọ