A. Oni 21:13 YCE

13 Gbogbo ijọ si ranṣẹ lọ bá awọn ọmọ Benjamini ti o wà ninu okuta Rimmoni sọ̀rọ, nwọn si fi alafia lọ̀ wọn.

Ka pipe ipin A. Oni 21

Wo A. Oni 21:13 ni o tọ