A. Oni 21:17 YCE

17 Nwọn si wipe, Ilẹ-iní kan yio wà fun awọn ti o ti sálà ni Benjamini, ki ẹ̀ya kan ki o má ba parun kuro ni Israeli.

Ka pipe ipin A. Oni 21

Wo A. Oni 21:17 ni o tọ