A. Oni 21:24 YCE

24 Nigbana li awọn ọmọ Israeli si lọ lati ibẹ̀, olukuluku enia si ẹ̀ya tirẹ̀, ati si idile tirẹ̀, nwọn si jade lati ibẹ̀ lọ olukuluku enia si ilẹ-iní tirẹ̀.

Ka pipe ipin A. Oni 21

Wo A. Oni 21:24 ni o tọ