A. Oni 21:8 YCE

8 Nwọn si wipe, Ewo ni ninu awọn ẹ̀ya Israeli ti kò tọ̀ OLUWA wá ni Mispe? Si kiyesi i, kò sí ẹnikan ni ibudó ti o ti Jabeṣi-gileadi wá si ijọ.

Ka pipe ipin A. Oni 21

Wo A. Oni 21:8 ni o tọ