A. Oni 3:29 YCE

29 Nwọn si pa ìwọn ẹgba marun ọkunrin ninu awọn ara Moabu ni ìgba na, gbogbo awọn ti o sigbọnlẹ, ati gbogbo awọn akọni ọkunrin; kò sí ọkunrin kanṣoṣo ti o sálà.

Ka pipe ipin A. Oni 3

Wo A. Oni 3:29 ni o tọ