A. Oni 3:8 YCE

8 Nitori na ibinu OLUWA ru si Israeli, o si tà wọn si ọwọ́ Kuṣani-riṣataimu ọba Mesopotamia: awọn ọmọ Israeli si sìn Kuṣani-riṣataimu li ọdún mẹjọ.

Ka pipe ipin A. Oni 3

Wo A. Oni 3:8 ni o tọ