A. Oni 4:16 YCE

16 Ṣugbọn Baraki lepa awọn kẹkẹ́, ati ogun na, titi dé Haroṣeti awọn orilẹ-ède: gbogbo ogun Sisera si ti oju idà ṣubu; ọkunrin kanṣoṣo kò si kù.

Ka pipe ipin A. Oni 4

Wo A. Oni 4:16 ni o tọ