A. Oni 4:2 YCE

2 OLUWA si tà wọn si ọwọ́ Jabini ọba Kenaani, ẹniti o jọba ni Hasori; olori ogun ẹniti iṣe Sisera, ẹniti ngbé Haroṣeti ti awọn orilẹ-ède.

Ka pipe ipin A. Oni 4

Wo A. Oni 4:2 ni o tọ