A. Oni 6:33 YCE

33 Nigbana ni gbogbo awọn Midiani ati awọn Amaleki, ati awọn ọmọ ìha ìla-õrùn kó ara wọn jọ pọ̀; nwọn rekọja, nwọn si dó li afonifoji Jesreeli.

Ka pipe ipin A. Oni 6

Wo A. Oni 6:33 ni o tọ