A. Oni 8:20 YCE

20 On si wi fun Jeteri arẹmọ rẹ̀ pe, Dide, ki o si pa wọn. Ṣugbọn ọmọkunrin na kò fà idà rẹ̀ yọ: nitori ẹ̀ru bà a, nitoripe ọmọde ni iṣe.

Ka pipe ipin A. Oni 8

Wo A. Oni 8:20 ni o tọ