A. Oni 8:33 YCE

33 O si ṣe, lojukanna ti Gideoni kú, li awọn ọmọ Israeli pada, nwọn si ṣe panṣaga tọ̀ Baalimu lọ, nwọn si fi Baaliberiti ṣe oriṣa wọn.

Ka pipe ipin A. Oni 8

Wo A. Oni 8:33 ni o tọ