A. Oni 9:27 YCE

27 Nwọn si jade lọ si oko, nwọn si ká eso-àjara wọn, nwọn si fọ́n eso na, nwọn si nṣe ariya, nwọn si lọ si ile oriṣa wọn, nwọn si jẹ, nwọn si mu, nwọn si fi Abimeleki ré.

Ka pipe ipin A. Oni 9

Wo A. Oni 9:27 ni o tọ