Amo 2:10 YCE

10 Emi mu nyin goke pẹlu lati ilẹ Egipti wá, mo si sìn nyin li ogoji ọdun là aginjù ja, lati ni ilẹ awọn Amori.

Ka pipe ipin Amo 2

Wo Amo 2:10 ni o tọ