Amo 4:8 YCE

8 Bẹ̃ni ilu meji tabi mẹta nrìn lọ si ilu kan, lati mu omi: ṣugbọn kò tẹ́ wọn lọrùn: sibẹ̀ ẹnyin kò ti ipadà sọdọ mi, li Oluwa wi.

Ka pipe ipin Amo 4

Wo Amo 4:8 ni o tọ