Amo 6:1 YCE

1 EGBE ni fun ẹniti ara rọ̀ ni Sioni, ati awọn ti o gbẹkẹ̀le oke nla Samaria, awọn ti a pè ni ikini ninu awọn orilẹ-ède, awọn ti ile Israeli tọ̀ wá!

Ka pipe ipin Amo 6

Wo Amo 6:1 ni o tọ