Dan 3:25 YCE

25 O si dahùn wipe, Wò o, mo ri ọkunrin mẹrin ni titu, nwọn sì nrin lãrin iná, nwọn kò si farapa, ìrisi ẹnikẹrin si dabi ti Ọmọ Ọlọrun.

Ka pipe ipin Dan 3

Wo Dan 3:25 ni o tọ