Esr 1:2 YCE

2 Bayi ni Kirusi ọba Persia wi pe, OLUWA, Ọlọrun ọrun, ti fi gbogbo ijọba aiye fun mi; o si ti pa a li aṣẹ lati kọ ile fun on ni Jerusalemu ti o wà ni Juda.

Ka pipe ipin Esr 1

Wo Esr 1:2 ni o tọ