30 Ati ninu awọn ọmọ Pahat-moabu Adma ati Kelali, Benaiah, Maaseiah, Mattaniah, Besaleeli, ati Binnui, ati Manasse.
31 Ati ninu awọn ọmọ Harimu; Elieseri, Isṣjah, Malkiah, Ṣemaiah, Ṣimeoni,
32 Benjamini, Malluki, ati Ṣemariah.
33 Ninu awọn ọmọ Haṣumu; Mattenai, Mattatta, Sabadi, Elifeleti, Jeremai, Manasse, ati Ṣimei.
34 Ninu awọn ọmọ Bani; Maadai, Amramu ati Ueli.
35 Benaiah, Bedeiah, Kellu,
36 Faniah, Meremoti, Eliaṣibu,