39 Ati Ṣelemiah, ati Natani, ati Adaiah,
40 Maknadebai, Saṣai, Ṣarai,
41 Asareeli, ati Ṣelemiah, Ṣemariah.
42 Ṣallumu, Amariah, ati Josefu.
43 Ninu awọn ọmọ Nebo; Jeieli, Mattitiah, Sabadi, Ṣebina, Jadau, ati Joeli, Benaiah.
44 Gbogbo awọn yi li o mu ajeji obinrin ba wọn gbe, omiran ninu wọn si ni obinrin nipa ẹniti nwọn li ọmọ.