Esr 4:6 YCE

6 Ati ni ijọba Ahasuerusi, ni ibẹ̀rẹ ijọba rẹ̀, ni nwọn kọwe ẹ̀sun lati fi awọn ara Juda ati Jerusalemu sùn.

Ka pipe ipin Esr 4

Wo Esr 4:6 ni o tọ