Esr 7:11 YCE

11 Eyi si ni atunkọ iwe na ti Artasasta ọba fi fun Esra alufa, akọwe, ani akọwe ọ̀rọ ofin Oluwa, ati ti aṣẹ rẹ̀ fun Israeli.

Ka pipe ipin Esr 7

Wo Esr 7:11 ni o tọ