Esr 8:1 YCE

1 WỌNYI ni awọn olori ninu awọn baba wọn, eyi ti a kọ sinu iwe itan-idile awọn ti o ba mi goke lati Babiloni wá, ni ijọba Artasasta ọba.

Ka pipe ipin Esr 8

Wo Esr 8:1 ni o tọ